0
Profile Picture

Yoruba proverbs

2 years ago
Ohun tó ṣe àkàlàmàgbò tó fi dẹ‌kun ẹ‌rin rínrín, tó bá ṣe igúnnugún, á wokoko mórí ẹyin ni.


Translation:
If what took laughter away from the crow had befallen the vulture, it would have been stuck brooding on its eggs.


Wisdom:
Be tolerant; different stroke for different folks.